I. Joh 4:9
I. Joh 4:9 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nipa eyi li a gbé fi ifẹ Ọlọrun hàn ninu wa, nitoriti Ọlọrun rán Ọmọ bíbi rẹ̀ nikanṣoṣo si aiye, ki awa ki o le yè nipasẹ rẹ̀.
Pín
Kà I. Joh 4I. Joh 4:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Nípa èyí ni a gbé fi ìfẹ́ Ọlọ́run hàn nínú wa, nítorí tí Ọlọ́run rán ọmọ bíbí rẹ̀ nìkan ṣoṣo sì ayé, kí àwa lè yè nípasẹ̀ rẹ̀.
Pín
Kà I. Joh 4