Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

I. A. Ọba 11:9YBCV(Bibeli Mimọ)

Oluwa si binu si Solomoni, nitori ọkàn rẹ̀ yipada kuro lọdọ Oluwa Ọlọrun Israeli, ti o ti fi ara hàn a lẹrinmeji.

I. A. Ọba 11:9BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

OLúWA bínú sí Solomoni nítorí ọkàn rẹ̀ ti yípadà kúrò lọ́dọ̀ OLúWA Ọlọ́run Israẹli, tí ó ti fi ara hàn án lẹ́ẹ̀méjì.

I. A. Ọba 11:9YCE(Yoruba Bible)

Inú bí OLUWA sí Solomoni, nítorí pé, ọkàn rẹ̀ ti yipada kúrò lọ́dọ̀ OLUWA Ọlọrun Israẹli tí ó fara hàn án nígbà meji