I. Sam 15:11
I. Sam 15:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
“Èmi káàánú gidigidi pé mo fi Saulu jẹ ọba, nítorí pé ó ti yípadà kúrò lẹ́yìn mi, kò sì pa ọ̀rọ̀ mi mọ́.” Inú Samuẹli sì bàjẹ́ gidigidi, ó sì ké pe OLúWA ní gbogbo òru náà.
Pín
Kà I. Sam 15