II. Kro 20:16
II. Kro 20:16 Bibeli Mimọ (YBCV)
Lọla sọ̀kalẹ tọ̀ wọn: kiyesi i, nwọn o gbà ibi igòke Sisi wá; ẹnyin o si ri wọn ni ipẹkun odò na, niwaju aginju Jerueli.