II. Kor 3:17
II. Kor 3:17 Bibeli Mimọ (YBCV)
Njẹ Oluwa li Ẹmí na: nibiti Ẹmí Oluwa ba si wà, nibẹ̀ li omnira gbé wà.
Pín
Kà II. Kor 3II. Kor 3:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ǹjẹ́ Olúwa ni Ẹ̀mí náà: níbi tí Ẹ̀mí Olúwa bá sì wà, níbẹ̀ ni òmìnira gbé wà
Pín
Kà II. Kor 3