Ṣe àfiwé gbogbo èyà
II. A. Ọba 12:2YBCV(Bibeli Mimọ)
Jehoaṣi si ṣe eyiti o tọ́ li oju Oluwa li ọjọ rẹ̀ gbogbo ninu eyiti Jehoiada alufa nkọ́ ọ.
II. A. Ọba 12:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jehoaṣi ṣe ohun tí ó tọ́ ní ojú OLúWA ní gbogbo ọdún tí Jehoiada àlùfáà fi àṣẹ fún un.
II. A. Ọba 12:2YCE(Yoruba Bible)
Ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ̀ ó ṣe ohun tí ó tọ́ lójú OLUWA nítorí pé Jehoiada alufaa ń tọ́ ọ sọ́nà.