Ṣe àfiwé gbogbo èyà
II. A. Ọba 17:39YBCV(Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn Oluwa Ọlọrun nyin ni ẹnyin o mã bẹ̀ru; on ni yio si gbà nyin lọwọ awọn ọta nyin gbogbo.
II. A. Ọba 17:39BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kúkú sin OLúWA Ọlọ́run rẹ; Òun ni ẹni náà tí yóò gbà yín kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá a yín.”
II. A. Ọba 17:39YCE(Yoruba Bible)
ṣugbọn kí wọn bẹ̀rù OLUWA Ọlọrun wọn, yóo sì gbà wọ́n lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá wọn.