Ṣe àfiwé gbogbo èyà
II. A. Ọba 18:5YBCV(Bibeli Mimọ)
O gbẹkẹle Oluwa Ọlọrun Israeli; ati lẹhin rẹ̀ kò si ẹniti o dabi rẹ̀ ninu gbogbo awọn ọba Juda, bẹ̃ni ṣãju rẹ̀ kò si ẹnikan.
II. A. Ọba 18:5BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Hesekiah sì gbẹ́kẹ̀lé OLúWA Ọlọ́run Israẹli. Kò sì ṣí ẹnìkan tí ó dàbí tirẹ̀ lára gbogbo àwọn ọba Juda, bóyá kí ó tó jẹ tàbí lẹ́yìn rẹ̀.
II. A. Ọba 18:5YCE(Yoruba Bible)
Hesekaya ní igbagbọ ninu OLUWA Ọlọrun Israẹli. Juda kò sì ní ọba mìíràn tí ó dà bíi rẹ̀, yálà ṣáájú rẹ̀ ni, tabi lẹ́yìn rẹ̀.