Ṣe àfiwé gbogbo èyà
II. A. Ọba 18:6YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitoriti o faramọ Oluwa, kò si lọ kuro lẹhin rẹ̀, ṣugbọn o pa ofin rẹ̀ wọnni mọ, ti Oluwa ti pa li aṣẹ fun Mose.
II. A. Ọba 18:6BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó súnmọ́ OLúWA, kò sì dẹ́kun láti tì í lẹ́yìn: ó sì pa òfin OLúWA mọ́ tí ó ti fi fún Mose.
II. A. Ọba 18:6YCE(Yoruba Bible)
Ó jẹ́ olóòótọ́ sí OLUWA, kò yapa kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀, ṣugbọn ó fi tọkàntọkàn pa àwọn òfin tí OLUWA fún Mose mọ́.