Ṣe àfiwé gbogbo èyà
II. A. Ọba 18:7YBCV(Bibeli Mimọ)
Oluwa si wà pẹlu rẹ̀; o si ṣe rere nibikibi ti o ba jade lọ: o si ṣọ̀tẹ si ọba Assiria, kò si sìn i mọ.
II. A. Ọba 18:7BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLúWA sì wà pẹ̀lú rẹ̀; ó sì ń ṣe rere nínú gbogbo ohun tí ó dáwọ́lé. Ó ṣe ọ̀tẹ̀ sí ọba Asiria kò sì sìn ín.
II. A. Ọba 18:7YCE(Yoruba Bible)
OLUWA wà pẹlu rẹ̀, ó sì ń ṣe àṣeyọrí ninu gbogbo ohun tí ó ń ṣe. Ó gba ara rẹ̀ lọ́wọ́ ọba Asiria, ó di òmìnira, ó kọ̀ kò sìn ín mọ́.