Ṣe àfiwé gbogbo èyà
II. A. Ọba 19:15YBCV(Bibeli Mimọ)
Hesekiah si gbadura niwaju Oluwa, o si wipe: Oluwa Ọlọrun Israeli, ti ngbe ãrin awọn kerubu, iwọ li Ọlọrun, ani iwọ nikanṣoṣo, ninu gbogbo awọn ilẹ-ọba aiye; iwọ li o dá ọrun on aiye.
II. A. Ọba 19:15BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Hesekiah gbàdúrà sí OLúWA: “OLúWA Ọlọ́run Israẹli, tí ń gbé ní àárín àwọn kérúbù, ìwọ nìkan ni Ọlọ́run lórí gbogbo ìjọba tí ó wà láyé, ìwọ ti dá ọ̀run àti ayé.
II. A. Ọba 19:15YCE(Yoruba Bible)
Ó gbadura pé, “OLUWA Ọlọrun Israẹli, tí ń gbé láàrin àwọn Kerubu, ìwọ nìkan ni Ọlọrun tí ń jọba lórí gbogbo ilẹ̀ ayé, ìwọ ni o dá ayé ati ọ̀run.