Ṣe àfiwé gbogbo èyà
II. Sam 9:1YBCV(Bibeli Mimọ)
DAFIDI si bere pe, ọkan ninu awọn ẹniti iṣe idile Saulu kù sibẹ bi? ki emi ki o le ṣe ore fun u nitori Jonatani.
II. Sam 9:1BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dafidi sì béèrè pé, ọ̀kan nínú àwọn ẹni tí ń ṣe ìdílé Saulu kù síbẹ̀ bí? Kí èmi lè ṣe oore fún un nítorí Jonatani.
II. Sam 9:1YCE(Yoruba Bible)
Ní ọjọ́ kan, Dafidi bèèrè pé, “Ǹjẹ́ ẹnikẹ́ni kù ninu gbogbo ìdílé Saulu tí mo lè ṣoore fún nítorí Jonatani?”
Pín
II. Sam 9YCE