II. Tes 2:4
II. Tes 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Òun yóò lòdì sí, yóò sì gbé ara rẹ̀ ga sí gbogbo ohun tí a ń pè ní Ọlọ́run tàbí tí a ń sìn, dé ibi pé yóò gbé ara rẹ̀ jókòó nínú tẹmpili Ọlọ́run, tí yóò sì pe ara rẹ̀ ní Ọlọ́run.
Pín
Kà II. Tes 2