Iṣe Apo 23:11
Iṣe Apo 23:11 Bibeli Mimọ (YBCV)
Li oru ijọ nã Oluwa duro tì i, o si wipe, Tujuka: nitori bi iwọ ti jẹri fun mi ni Jerusalemu, bẹ̃ni iwọ kò le ṣaijẹrí ni Romu pẹlu.