Iṣe Apo 7:59-60
Iṣe Apo 7:59-60 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nwọn sọ Stefanu li okuta, o si nképe Oluwa wipe, Jesu Oluwa, gbà ẹmí mi. O si kunlẹ, o kigbe li ohùn rara pe, Oluwa, má kà ẹ̀ṣẹ yi si wọn li ọrùn. Nigbati o si wi eyi, o sùn.
Pín
Kà Iṣe Apo 7