Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Amo 3:3YBCV(Bibeli Mimọ)

Ẹni meji lè rìn pọ̀, bikòṣepe nwọn rẹ́?

Amo 3:3BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ẹni méjì ha à le rìn pọ̀ láìjẹ́ pé wọ́n ti pinnu láti ṣe bẹ?

Amo 3:3YCE(Yoruba Bible)

“Ṣé eniyan meji lè jọ máa lọ sí ibìkan láìjẹ́ pé wọ́n ní àdéhùn?