Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Amo 3:7YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitori Oluwa Ọlọrun kì o ṣe nkan kan, ṣugbọn o fi ohun ikọ̀kọ rẹ̀ hàn awọn woli iranṣẹ rẹ̀.
Pín
Amo 3YBCVAmo 3:7BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítòótọ́ OLúWA Olódùmarè kò ṣe ohun kan láìfi èrò rẹ̀ hàn fun àwọn wòlíì ìránṣẹ́ rẹ̀.
Pín
Amo 3BMYOAmo 3:7YCE(Yoruba Bible)
“Dájúdájú OLUWA Ọlọrun kì í ṣe ohunkohun láì kọ́kọ́ fi han àwọn wolii, iranṣẹ rẹ̀.
Pín
Amo 3YCE