Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Amo 4:12YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitorina, bayi li emi o ṣe si ọ, iwọ Israeli: ati nitoriti emi o ṣe eyi si ọ, mura lati pade Ọlọrun rẹ, iwọ Israeli.
Pín
Amo 4YBCVAmo 4:12BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Nítorí náà, èyí ni ohun tí èmi yóò ṣe sí i yín, Israẹli, àti nítorí tí èmi ó ṣe èyí sí i yín, ẹ múra láti pàdé Ọlọ́run yín, ẹ̀yin Israẹli.”
Pín
Amo 4BMYOAmo 4:12YCE(Yoruba Bible)
Nítorí náà, n óo jẹ yín níyà, ẹ̀yin ọmọ Israẹli; nítorí irú ìyà tí n óo fi jẹ yín, ẹ múra sílẹ̀ de ìdájọ́ Ọlọrun yín, ẹ̀yin ọmọ Israẹli!”
Pín
Amo 4YCE