Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Amo 5:15YBCV(Bibeli Mimọ)
Ẹ korira ibi, ẹ si fẹ́ ire, ki ẹ si fi idajọ gunlẹ ni bodè; boya Oluwa Ọlọrun awọn ọmọ-ogun yio ṣe ojurere si iyokù Josefu.
Pín
Amo 5YBCVAmo 5:15BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kórìíra búburú kí o sì fẹ́ rere dúró ní orí òtítọ́ ní ilé ẹjọ́ bóyá OLúWA Ọlọ́run alágbára yóò síjú àánú wo ọmọ Josẹfu tó ṣẹ́kù.
Pín
Amo 5BMYOAmo 5:15YCE(Yoruba Bible)
Ẹ kórìíra ibi, kí ẹ sì fẹ́ ire, ẹ jẹ́ kí ìdájọ́ òdodo gbilẹ̀ lẹ́nu ibodè yín; bóyá OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun yóo ṣàánú fún àwọn ọmọ ilé Josẹfu yòókù.
Pín
Amo 5YCE