Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Amo 8:11YBCV(Bibeli Mimọ)
Kiyesi i, ọjọ na de, li Oluwa Ọlọrun wi, emi o rán iyàn wá si ilẹ na, kì iṣe iyàn onjẹ, tabi ongbẹ fun omi, ṣugbọn iyàn gbigbọ́ ọ̀rọ Oluwa
Pín
Amo 8YBCVAmo 8:11BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ọjọ́ ń bọ̀,” ni OLúWA Olódùmarè wí, “nígbà tí èmi yóò rán ìyàn sí ilẹ̀ náà, kì í ṣe ìyàn oúnjẹ tàbí òǹgbẹ fún omi. Ṣùgbọ́n ìyàn gbígbọ́ ọ̀rọ̀ OLúWA.
Pín
Amo 8BMYOAmo 8:11YCE(Yoruba Bible)
OLUWA Ọlọrun ní, “Ọjọ́ ń bọ̀ tí n óo rán ìyàn sí ilẹ̀ náà; kì í ṣe ìyàn, oúnjẹ, tabi ti omi, ìran láti ọ̀dọ̀ OLUWA ni kò ní sí.
Pín
Amo 8YCE