Kol 1:15 - Compare All Versions
Kol 1:15 YCE (Yoruba Bible)
Eniyan kò lè rí Ọlọrun, ṣugbọn ọmọ yìí ni àwòrán rẹ̀, òun ni àkọ́bí ohun gbogbo tí a dá.
Pín
Kol 1 YCEKol 1:15 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kristi ni àwòrán Ọlọ́run tí a kò le rí, àkọ́bí gbogbo ẹ̀dá.
Pín
Kol 1 BMYO