Ọ̀rọ ẹnu ọlọgbọ̀n li ore-ọfẹ; ṣugbọn ète aṣiwère ni yio gbe ara rẹ̀ mì.
Ọ̀rọ̀ ẹnu ọlọ́gbọ́n a máa bu iyì kún un, ṣugbọn ẹnu òmùgọ̀ ni yóo pa á.
Ọ̀rọ̀ tí ó wá láti ẹnu ọlọ́gbọ́n a máa ní oore-ọ̀fẹ́ ṣùgbọ́n ètè òmùgọ̀ fúnrarẹ̀ ni yóò parun.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò