Ẹniti o wà iho ni yio bọ́ sinu rẹ̀; ati ẹniti o si njá ọgbà tútù, ejo yio si bù u ṣán.
Ẹni tí ó gbẹ́ kòtò ni yóo jìn sinu rẹ̀, ẹni tí ó bá já ọgbà wọlé ni ejò yóo bùjẹ.
Ẹnikẹ́ni tí ó bá gbẹ́ kòtò, ó le è ṣubú sínú rẹ̀; ẹnikẹ́ni tí ó bá la inú ògiri, ejò le è ṣán an.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò