Oni 12:6-7
Oni 12:6-7 Bibeli Mimọ (YBCV)
Tabi ki okùn fadaka ki o to tu, tabi ki ọpọn wura ki o to fọ, tabi ki ìṣa ki o to fọ nibi isun, tabi ki ayika-kẹkẹ ki o to kán nibi kanga. Nigbana ni erupẹ yio pada si ilẹ bi o ti wà ri, ẹmi yio si pada tọ̀ Ọlọrun ti o fi i funni.
Pín
Kà Oni 12