Ọba titun miran si wa ijẹ ni Egipti, ti kò mọ́ Josefu.
Nígbà tí ó yá, ọba titun kan tí kò mọ Josẹfu gorí oyè, ní ilẹ̀ Ijipti.
Nígbà náà ni ọba tuntun mìíràn tí kò mọ Josẹfu jẹ ní ilẹ̀ Ejibiti.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò