Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Eks 39:42YBCV(Bibeli Mimọ)
Gẹgẹ bi gbogbo ohun ti OLUWA fi aṣẹ fun Mose, bẹ̃li awọn ọmọ Israeli ṣe gbogbo iṣẹ na.
Pín
Eks 39YBCVEks 39:42BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọ Israẹli ti ṣe gbogbo iṣẹ́ náà gẹ́gẹ́ bí OLúWA ti pàṣẹ fún Mose.
Pín
Eks 39BMYOEks 39:42YCE(Yoruba Bible)
Gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose, ni àwọn eniyan Israẹli ṣe gbogbo iṣẹ́ náà.
Pín
Eks 39YCE