Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Eks 39:43YBCV(Bibeli Mimọ)
Mose si bojuwò gbogbo iṣẹ na, si kiyesi i, nwọn si ṣe e bi OLUWA ti palaṣẹ, bẹ̃ gẹgẹ ni nwọn ṣe e; Mose si sure fun wọn.
Pín
Eks 39YBCVEks 39:43BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mose bẹ iṣẹ́ náà wò, ó sì rí i wí pé wọ́n ti ṣe é gẹ́gẹ́ bí OLúWA ti pàṣẹ. Nítorí náà Mose sì bùkún fún wọn.
Pín
Eks 39BMYOEks 39:43YCE(Yoruba Bible)
Mose wo gbogbo iṣẹ́ náà, ó rí i pé wọ́n ṣe é gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pa á láṣẹ, Mose sì súre fún wọn.
Pín
Eks 39YCE