Eks 40:34-35
Eks 40:34-35 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nigbana li awọsanma bò agọ́ ajọ, ogo OLUWA si kún inu agọ́ na. Mose kò si le wọ̀ inu agọ́ ajọ lọ, nitoriti awọsanma wà lori rẹ̀, ogo OLUWA si kun inu agọ́ na.
Pín
Kà Eks 40Nigbana li awọsanma bò agọ́ ajọ, ogo OLUWA si kún inu agọ́ na. Mose kò si le wọ̀ inu agọ́ ajọ lọ, nitoriti awọsanma wà lori rẹ̀, ogo OLUWA si kun inu agọ́ na.