Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Esek 11:19YBCV(Bibeli Mimọ)
Emi o si fun wọn li ọkàn kan, emi o si fi ẹmi titun sinu nyin; emi o si mu ọkàn okuta kuro lara wọn, emi o si fun wọn li ọkàn ẹran
Pín
Esek 11YBCVEsek 11:19BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò fún wọn ní ọ̀kankan; èmi yóò sì fi ẹ̀mí tuntun sínú wọn, Èmi yóò mú ọkàn òkúta kúrò lára wọn, èmi yóò sì fún wọn ní ọkàn tó rọ̀ bí ara ẹran.
Pín
Esek 11BMYOEsek 11:19YCE(Yoruba Bible)
Ó ní, mo sọ pé, n óo fún wọn ní ọkàn kan, n óo fi ẹ̀mí titun sí wọn ninu. N óo yọ ọkàn òkúta kúrò láyà wọn, n óo sì fún wọn ní ọkàn ẹran
Pín
Esek 11YCE