Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Esek 13:3YBCV(Bibeli Mimọ)
Bayi li Oluwa Ọlọrun wi, egbé ni fun awọn aṣiwere woli, ti nwọn ntẹ̀le ẹmi ara wọn, ti wọn kò si ri nkan!
Pín
Esek 13YBCVEsek 13:3BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Báyìí ni OLúWA Olódùmarè wí: Ègbé ni fún àwọn aṣiwèrè wòlíì tó ń tẹ̀lé ẹ̀mí ara wọn tí wọn kò sì rí nǹkan kan!
Pín
Esek 13BMYOEsek 13:3YCE(Yoruba Bible)
OLUWA Ọlọrun ní, “Ègbé ni fún àwọn òmùgọ̀ wolii tí wọn ń tẹ̀lé ìmọ̀ ara wọn láì jẹ́ pé wọ́n ríran rárá.
Pín
Esek 13YCE