Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Esek 16:60YBCV(Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn emi o ranti majẹmu mi pẹlu rẹ, ni ọjọ ewe rẹ, emi o si gbe majẹmu aiyeraiye kalẹ fun ọ.
Pín
Esek 16YBCVEsek 16:60BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Síbẹ̀ èmi yóò rántí májẹ̀mú tí mo bá ọ ṣe nígbà èwe rẹ, èmi yóò sì bá ọ dá májẹ̀mú láéláé.
Pín
Esek 16BMYOEsek 16:60YCE(Yoruba Bible)
Sibẹsibẹ, n óo ranti majẹmu tí mo bá ọ dá ní ìgbà èwe rẹ. N óo sì bá ọ dá majẹmu tí kò ní yẹ̀ títí lae.
Pín
Esek 16YCE