Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Esek 18:23YBCV(Bibeli Mimọ)
Emi ha ni inu-didùn rara pe ki enia buburu ki o kú? ni Oluwa Ọlọrun wi: kò ṣepe ki o yipada kuro ninu ọ̀na rẹ̀, ki o si yè?
Pín
Esek 18YBCVEsek 18:23BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ǹjẹ́ èmi ha ni inú dídùn si ikú ènìyàn búburú bí í? Ní OLúWA Olódùmarè wí pé, dípò èyí inú mi kò ha ni i dùn nígbà tó ba yípadà kúrò ni àwọn ọ̀nà búburú rẹ̀ kí ó sì yè?
Pín
Esek 18BMYOEsek 18:23YCE(Yoruba Bible)
OLUWA ní: “A máa ṣe pé mo ní inú dídùn sí ikú ẹlẹ́ṣẹ̀ ni? Ṣebí ohun tí mo fẹ́ ni pé kí ó yipada kúrò lọ́nà burúkú rẹ̀, kí ó sì yè.
Pín
Esek 18YCE