Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Esek 18:32YBCV(Bibeli Mimọ)

Nitoripe emi kò ni inu didùn si ikú ẹniti o kú, ni Oluwa Ọlọrun wi: nitorina ẹ yi ara nyin pada, ki ẹ si yè.

Esek 18:32BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Nítorí pé inú mi kò dùn sí ikú ẹnikẹ́ni ni OLúWA Olódùmarè wí. Nítorí náà, ẹ yípadà kí ẹ sì yè!

Esek 18:32YCE(Yoruba Bible)

N kò ní inú dídùn sí ikú ẹnikẹ́ni, nítorí náà, ẹ yipada kí ẹ lè yè. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”