Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Esek 20:19YBCV(Bibeli Mimọ)
Emi ni Oluwa Ọlọrun nyin: ẹ rìn ninu aṣẹ mi, ẹ si pa idajọ mi mọ, ẹ si ṣe wọn
Pín
Esek 20YBCVEsek 20:19BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi ni OLúWA Ọlọ́run yín, ẹ tẹ̀lé àṣẹ mi, kí ó sì pa òfin mi mọ́.
Pín
Esek 20BMYOEsek 20:19YCE(Yoruba Bible)
Mo ní èmi OLUWA ni Ọlọrun yín. Ẹ máa rìn ní ọ̀nà mi, kí ẹ sì máa pa òfin mi mọ́.
Pín
Esek 20YCE