Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Esek 21:26YBCV(Bibeli Mimọ)
Bayi li Oluwa Ọlọrun wi; Mu fila ọba kuro, si ṣi ade kuro; eyi kò ni jẹ ọkanna: gbe ẹniti o rẹlẹ ga, si rẹ̀ ẹniti o ga silẹ.
Pín
Esek 21YBCVEsek 21:26BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
èyí yìí ní ohun tí OLúWA Olódùmarè wí, tú ìwérí kúrò kí o sì gbé adé kúrò. Kò ní rí bí ti tẹ́lẹ̀, ẹni ìgbéga ni a yóò sì rẹ̀ sílẹ̀.
Pín
Esek 21BMYOEsek 21:26YCE(Yoruba Bible)
Ẹ ṣí fìlà, kí ẹ sì ṣí adé ọba kúrò lórí, gbogbo nǹkan kò ní wà bí wọ́n ṣe rí. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀. Ẹ gbé àwọn tí ipò wọn rẹlẹ̀ ga, kí ẹ sì rẹ àwọn tí ipò wọn wà lókè sílẹ̀.
Pín
Esek 21YCE