Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Esek 23:35YBCV(Bibeli Mimọ)

Nitorina bayi li Oluwa Ọlọrun wi; Nitoripe iwọ ti gbagbe mi ti o si ti sọ mi si ẹhìn rẹ, nitorina iwọ rù ifẹkufẹ rẹ pẹlu ati panṣaga rẹ

Esek 23:35BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

“Nítorí náà báyìí ní OLúWA Olódùmarè wí: Níwọ́n bí ìwọ ti gbàgbé mi, tí ìwọ sì ti fi mi sí ẹ̀yìn rẹ, ìwọ gbọdọ̀ gba àbájáde ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ àti panṣágà rẹ.”

Esek 23:35YCE(Yoruba Bible)

Nítorí náà, OLUWA Ọlọrun ní, “Nítorí pé o ti gbàgbé mi, o sì ti kọ̀ mí sílẹ̀, o óo jìyà ìṣekúṣe ati àgbèrè rẹ.”