Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Esek 33:7YBCV(Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni, iwọ ọmọ enia, emi ti fi ọ ṣe oluṣọ́ fun ile Israeli; nitorina iwọ o gbọ́ ọ̀rọ li ẹnu mi, iwọ o si kìlọ fun wọn lati ọdọ mi.
Pín
Esek 33YBCVEsek 33:7BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ọmọ ènìyàn, èmi fi ọ ṣe alóre fún ilé Israẹli; nítorí náà gbọ́ ọ̀rọ̀ tí mo sọ, kí o sì fún wọn ni ìkìlọ̀ láti ọ̀dọ̀ mi.
Pín
Esek 33BMYOEsek 33:7YCE(Yoruba Bible)
“Ọmọ eniyan, ìwọ ni mo yàn ní olùṣọ́ fún ilé Israẹli; nígbàkúùgbà tí o bá gbọ́ ọ̀rọ̀ kan lẹ́nu mi, o níláti bá mi kìlọ̀ fún wọn.
Pín
Esek 33YCE