Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Esek 34:15YBCV(Bibeli Mimọ)
Emi o bọ́ ọwọ́-ẹran mi, emi o si mu ki nwọn dubulẹ, li Oluwa Ọlọrun wi.
Pín
Esek 34YBCVEsek 34:15BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi fúnra mi yóò darí àgùntàn mi, èmi yóò mú wọn dùbúlẹ̀, ni OLúWA Olódùmarè wí.
Pín
Esek 34BMYOEsek 34:15YCE(Yoruba Bible)
Èmi fúnra mi ni n óo jẹ́ olùṣọ́ àwọn aguntan mi, n óo sì mú wọn dùbúlẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni èmi OLUWA Ọlọrun sọ.
Pín
Esek 34YCE