Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Esek 36:25YBCV(Bibeli Mimọ)
Nigbana ni emi o fi omi mimọ́ wọ́n nyin, ẹnyin o si mọ́: emi o si wẹ̀ nyin mọ́ kuro ninu gbogbo ẹgbin nyin ati kuro ninu gbogbo oriṣa nyin.
Pín
Esek 36YBCVEsek 36:25BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò wọ́n omi tó mọ́ sí yín lára ẹ̀yin yóò sì mọ́; Èmi yóò sì fọ̀ yín mọ́ kúrò nínú gbogbo ìwà èérí yin gbogbo àti kúrò nínú gbogbo òrìṣà yin.
Pín
Esek 36BMYOEsek 36:25YCE(Yoruba Bible)
N óo wọ́n omi mímọ́ si yín lórí, àìmọ́ yín yóo sì di mímọ́. N óo wẹ̀ yín mọ́ kúrò ninu gbogbo ìbọ̀rìṣà yín.
Pín
Esek 36YCE