Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Esek 8:12YBCV(Bibeli Mimọ)
Nigbana li o si wi fun mi pe, Ọmọ enia iwọ ri ohun ti awọn agbà ile Israeli nṣe li okunkùn, olukuluku ninu iyará oriṣa tirẹ̀? nitori nwọn wipe, Oluwa kò ri wa; Oluwa ti kọ̀ aiye silẹ.
Pín
Esek 8YBCVEsek 8:12BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sọ fún mi pé, “Ọmọ ènìyàn, ṣé o ti rí ohun tí àwọn àgbàgbà ilé Israẹli ń ṣe nínú òkùnkùn, olúkúlùkù ní yàrá òrìṣà rẹ̀? Wọ́n ní, ‘OLúWA kò rí wa; OLúWA ti kọ̀ ilé náà sílẹ̀.’ ”
Pín
Esek 8BMYOEsek 8:12YCE(Yoruba Bible)
OLUWA tún bi mí pé: “Ọmọ eniyan, ṣé o rí ohun tí àwọn àgbààgbà ilé Israẹli ń ṣe ninu òkùnkùn? Ṣé o rí ohun tí olukuluku ń ṣe ninu yàrá tí ó kún fún àwòrán ère oriṣa? Wọ́n ń wí pé, ‘OLUWA kò rí wa, ó ti kọ ilẹ̀ wa sílẹ̀.’ ”
Pín
Esek 8YCE