Gal 6:7
Gal 6:7 Yoruba Bible (YCE)
Ẹ má tan ara yín jẹ: eniyan kò lè mú Ọlọrun lọ́bọ. Ohunkohun tí eniyan bá gbìn ni yóo ká.
Pín
Kà Gal 6Gal 6:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Kí a má ṣe tàn yín jẹ; a kò lè gan Ọlọ́run: nítorí ohunkóhun tí ènìyàn bá fúnrúgbìn, òhun ni yóò sì ká.
Pín
Kà Gal 6