Gẹn 13:10
Gẹn 13:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Lọti sì gbójú sókè, ó sì ri wí pé gbogbo pẹ̀tẹ́lẹ̀ Jordani ni omi rin dáradára bí ọgbà OLúWA, bí ilẹ̀ Ejibiti, ní ọ̀nà Soari. (Èyí ní ìṣáájú kí OLúWA tó pa Sodomu àti Gomorra run).
Pín
Kà Gẹn 13