Gẹn 32:32
Gẹn 32:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ìdí nìyí tí àwọn ọmọ Israẹli kì í fi í jẹ iṣan tí ó wà ní ọ̀ọ́kán ibi tí eegun itan ti bẹ̀rẹ̀ títí di òní olónìí, nítorí níbi iṣan náà ni a ti fọwọ́ kan ibi tí egungun itan Jakọbu ti bẹ̀rẹ̀.
Pín
Kà Gẹn 32