Gẹn 9:12-13
Gẹn 9:12-13 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọlọrun si wipe, Eyiyi li àmi majẹmu mi ti mo ba nyin dá, ati gbogbo ẹdá alãye ti o wà pẹlu nyin, fun atirandiran: Mo fi òṣumare mi si awọsanma, on ni yio si ma ṣe àmi majẹmu mi ti mo ba aiye dá.
Pín
Kà Gẹn 9