Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Hos 11:4YBCV(Bibeli Mimọ)
Mo fi okùn enia fà wọn, ati idè ifẹ: mo si ri si wọn bi awọn ti o mu ajàga kuro li ẹrẹkẹ wọn, mo si gbe onjẹ kalẹ niwaju wọn.
Pín
Hos 11YBCVHos 11:4BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Mo fi okùn ènìyàn fà wọ́n àti ìdè ìfẹ́. Mo mú àjàgà kúrò ni ọrùn wọn, Mo sì fi ara balẹ̀ fún wọn ni oúnjẹ.
Pín
Hos 11BMYOHos 11:4YCE(Yoruba Bible)
Mo fà wọ́n mọ́ra pẹlu okùn àánú ati ìdè ìfẹ́, mo dàbí ẹni tí ó tú àjàgà kúrò ní ẹ̀rẹ̀kẹ́ wọn, mo sì bẹ̀rẹ̀, mo gbé oúnjẹ kalẹ̀ níwájú wọn.
Pín
Hos 11YCE