Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Hos 14:4YBCV(Bibeli Mimọ)
Emi o wo ifàsẹhìn wọn sàn, emi o fẹ wọn lọfẹ: nitori ibinu mi yí kuro lọdọ rẹ̀.
Pín
Hos 14YBCVHos 14:4BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Èmi wo àgàbàgebè wọn sàn, Èmi ó sì fẹ́ràn wọn, lọ́fẹ̀ẹ́, nítorí ìbínú mi ti yípadà kúrò lọ́dọ̀ wọn.
Pín
Hos 14BMYOHos 14:4YCE(Yoruba Bible)
Ọlọrun ní, “N óo gba ìwà aiṣootọ lọ́wọ́ wọn, n óo fẹ́ wọn tọkàntọkàn, nítorí n kò bínú sí wọn mọ́.
Pín
Hos 14YCE