Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Hos 5:4YBCV(Bibeli Mimọ)
Iṣe wọn kì o jọ̀wọ wọn lati yipadà si Ọlọrun wọn: nitori ẹmi agbère wà lãrin wọn, nwọn kò si mọ̀ Oluwa.
Pín
Hos 5YBCVHos 5:4BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ìṣe wọn kò gbà wọ́n láààyè láti padà sí ọ̀dọ̀ Ọlọ́run wọn. Ẹ̀mí àgbèrè wà ni ọkàn wọn, wọn kò sì mọ OLúWA.
Pín
Hos 5BMYOHos 5:4YCE(Yoruba Bible)
Gbogbo ibi tí wọn ń ṣe, kò jẹ́ kí wọ́n lè pada sọ́dọ̀ Ọlọrun wọn, nítorí pé ọkàn wọn kún fún ẹ̀mí àgbèrè, wọn kò sì mọ OLUWA.
Pín
Hos 5YCE