Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Hos 6:1YBCV(Bibeli Mimọ)
Ẹ wá, ẹ jẹ ki a yipadà si Oluwa: nitori o ti fà wa ya, on o si mu wa lara da; o ti lù wa, yio si tun wa dì.
Pín
Hos 6YBCVHos 6:1BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a padà sọ́dọ̀ OLúWA ó ti fà wá ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ ṣùgbọ́n yóò mú wa láradá Ó ti pa wá lára ṣùgbọ́n yóò dí ojú ọgbẹ́ wa.
Pín
Hos 6BMYOHos 6:1YCE(Yoruba Bible)
Wọn óo wí pé, “Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á pada sọ́dọ̀ OLUWA; nítorí bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti fà wá ya, sibẹ yóo wò wá sàn; ó ti pa wá lára lóòótọ́, ṣugbọn yóo di ọgbẹ́ wa.
Pín
Hos 6YCE