Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Hos 9:17YBCV(Bibeli Mimọ)
Ọlọrun mi yio sọ wọn nù, nitoriti nwọn kò fetisi tirẹ̀; nwọn o si di alarinkiri lãrin awọn keferi.
Pín
Hos 9YBCVHos 9:17BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọlọ́run mi yóò kọ̀ wọ́n sílẹ̀ nítorí pé wọn kò gbọ́rọ̀ sí i; wọn yóò sì di alárìnkiri láàrín àwọn orílẹ̀-èdè.
Pín
Hos 9BMYOHos 9:17YCE(Yoruba Bible)
Ọlọrun mi yóo pa wọ́n run, nítorí pé wọn kò fetí sí ọ̀rọ̀ rẹ̀; wọn yóo di alárìnkiri láàrin àwọn orílẹ̀-èdè.
Pín
Hos 9YCE