Kọrin si Oluwa: nitori o ti ṣe ohun didara: eyi di mimọ̀ ni gbogbo aiye.
Ẹ kọ orin ìyìn sí OLUWA nítorí ó ṣe nǹkan tí ó lógo, jẹ́ kí èyí di mímọ̀ ní gbogbo ayé.
Kọ orin sí OLúWA, nítorí ó ti ṣe ohun tí ó lógo, jẹ́ kí èyí di mí mọ̀ fún gbogbo ayé.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò